LyricsMusicVideos

Monique ~ Ride On [Music, MP3, Video & Lyrics]

Here is the Music, video and lyrics of “Ride On” by Nigerian Gospel Music Minister with the official music video.

Related Articles
CLICK HERE TO DOWNLOAD SONG MP3

DOWNLOAD

Watch Video Ride On By Monique

Lyrics: Ride On By Monique

Verse 1:
Agbára Olórun mbe níbí.
The Power of GOD is here.
Èmí Olórun mbe níbí.
The Spirit of GOD is here.

Chorus:
Momòpé bímobá képè é, Óma foùn.
Momòpé bímobá képè é, Á sògo.
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow.

Ride On, Ride On, Ride On.
Èmí oooo.
Ride On, Ride On, Ride On.

Verse 2:
Let my ears belong to you so all i hear is you.
Let my heart belong to you.
So all i do is you.
Shield me from the power of sin.
Let them gat nothing on me.
Holy Spirit, gbàmí tán.

Chorus:
Momòpé bímobá képè é, Óma foùn.
Momòpé bímobá képè é, Á sògo.
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow.

Ride On, Ride On, Ride On.
Èmí oooo.
Ride On, Ride On, Ride On.

Chants:
Agbára Olórun mbe láyé mi.
Agbára tóh borí ohun gbogbo.
Who art thou oh mountain níwájú Oba gbogbo ayé.
Olúwa tóh pò nípá àti agbára.
Òkan soso òrò tí nso gbogbo òrò.
Òrò gbénú omi adágún.
Òrò gbénú omi òkun ru.
Ìjìnlè nlá Atófaratì bí òkè.
Mopá tàsetàse L’órúko JÉSÙ Kristì.
Egbé oríiyín sókè, èyin enu ònà, kí asì gbé e yín sókè èyin ilèkùn ayérayé, kí Oba ògo kíó wolé wá.
Àkóbí nú àwon òkú, òdó àgùntàn tíó fèmí rè lé’lè fún wa.
Olùdámòràn, igi òkìkí, àpáta aìí dìgbòlù, òkè táò l’esí.
Òjìjí àti ìmólè.

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button

Adblock Detected

Please disable your Adblocker before having access to this site